У нас вы можете посмотреть бесплатно Oro Ti Sele o ! Awon Oyo Ti Fi Ẹjo Saoty Arewa Sun Lori Itan Ki Tan To Pa Nipa Alaafin Oyo или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Oro Ti Sele o ! Awon Oyo Ti Fi Ẹjo Saoty Arewa Sun Lori Itan Ki Tan To Pa Nipa Alaafin Oyo Ẹma Jẹki Ẹsin Sọ Wa Di Were" Baba Akeugbagold Ju Bombu Oro Fun Gbogbo Elesin Lori Rogbodiyan Tonlo ITAN ALAFIN OYO ATI ALFA ALALUKIMBA - Alhaji Saoty Arewa at Al-Amowiy 2024ALỌ LÁSÁN Aláàfin Ọ̀yọ́ ijefa ni Alafin Adeyemi Atiba tó ńṣe ọmọ Aláàfin Adewinbi Atiba. Aláàfin Abiodun Adewinbi Atiba ni Aláàfin ketadinlogoji òun sini Aláàfin àkókò tó kọ́kọ́ je sì Ọ̀yọ́ toni 1837-1860. Arẹmọ rẹ Adelu Atiba ni Alafin kejidinlogoji oun ni Aláàfin kejì tó jẹ́ sì Ọ̀yọ́ toni 1860-1875. Aláàfin ijefa tí Saoty Arewa ń sọ yí ni àbúrò Alafin Adelu Aláàfin Abiodun Adewinbi Atiba lọ jọ bí wọn nigbati Ọ̀yọ́ kò gbà kí Aremo Adelu tó ń jẹ Lawani Amubieya je Ọba ní Adeyemi Atiba jẹ Alafin lodun 1875-1905 Musulumi ni Aláàfin Atiba baba wọn Musulumi sini àwọn ọmọ rẹ Aláàfin Atiba lo sì kọ masalasi sì Ọ̀yọ́ toni ṣáájú kò tó jẹ́ Aláàfin lo tí ko. Láti wá palo bayi pe Alfa ni baba Ọba je alọ agbelero tí koni ẹri kan ni Ọ̀yọ́ tàbí àkọsílẹ̀ kan. Kí Saoty Arewa je ka mọ ibi tó ti rí Ìtàn rẹ pẹlu ẹri tó yanjú, Alfa kiise baba ọba ọba loni ìlú ó bá lórí gbogbo ìlú ohun sini Aláṣẹ ìlú kiise Alfa tó jẹ́ olórí ìjọ nilẹ Yorùbá. Subscribe to this channel and turn on post notification © Follow Good example Tv on Facebook © Instagram @Good Example © Tiktok @Good Example.