У нас вы можете посмотреть бесплатно PE BABA IJESHA JADE LEWON KO TO N TA N YA YO SI O - PRINCESS LO F'OUN LEDE,GBE IKILO SITA - YORUBA или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
PE BABA IJESHA JADE LEWON KO TO N TA N YA YO SI O - PRINCESS LO F'OUN LEDE,GBE IKILO SITA - YORUBA Pe Baba Ijẹsha jade lẹwọn ko to n ta n ya yọ si o, Princess lo f'oun lede, gbé ìkìlọ̀ síta lẹ́yìn ìtúsílẹ̀ Baba Ijesha lọ́gba ẹ̀wọ̀n Ọkọ mi ma n mu àwọn ọmọ wa lọ sí abẹtẹ, wọn o we pepa, wọn o tanna sí, wọn o sì má fa - Obinrin kan lo sọ fún iléẹjọ́ bẹẹ Iyooku ara mi gbọdọ jẹ ṣinṣin láàrin ọsẹ mẹrin ti mo ba jade l'ayé - Fayose lo wí bẹẹ fún ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì Ìpàdé àpérò ẹgbẹ oselu PDP waye o, gẹgẹ bi wọn ti kọwe rẹ, wọn la o ni le se a si ti se, oju ti irọ wọn lorin tawọn ̣ọmọ ẹgbẹ oselu naa nkọ. Ileesẹ Ọlọpa nawọ gan Baba kan f'ẹsun jija ibale awọn ọmọbìnrin rẹ mẹta nipinlẹ Delta Adeleke kan n nawo jẹ ni ti ẹ ni o, ko sisẹ kankan lori eto ẹkọ, ẹgbẹ oselu APC lo j'okuta ọrọ sijọba PDP lawọn naa ba fesi pe aye n gbọ, awọn eeyan naa si mọ pe Ìjọba Adeleke n se bẹbẹ lỌsun. Àpáta ti ẹ n fọ yi n sàkóbá fún wa o, àwọn èèyàn ìlú kan l'Ondo, níbi tí ìró àpáta ti ń mú kí ilé mì tìtì, fọ́ ògiri ọ̀pọ̀ ilé, tí ìdààmú sì ń báwọn olùgbé ibẹ̀ pariwo sita