У нас вы можете посмотреть бесплатно OBA GHANDI AFOLABI OLAOYE TU IGBIMO ALASE EGBE OGBOMOSO PARAPO AGBAAYE NI WON BA FARIGA SI SOUN OGBO или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
OBA GHANDI AFOLABI OLAOYE TU IGBIMO ALASE EGBE OGBOMOSO PARAPO AGBAAYE NI WON BA FARIGA FUN SOUN OGBOMOSO Ọba Ghandi tu igbimọ alasẹ ẹgbẹ Ogbomọsọ parapọ agbaaye ka, ẹgbẹ Ogbomọsọ parapọ agbaaye fọnmu pe Ọba ko ni agbara lati tu ẹgbẹ àwọn ka O ma se o, gbajúmọ̀ adẹ́rìnínpòṣónú, Sanku Comedy pade iku ojiji lẹ́yìn tó se kongẹ ìjàmbá ọkọ̀ lọ́jọ́ Ajé Mọnde O d'ofin o, Iléeṣẹ́ ọlọ́páà Eko ti fi òfin de bí àwọn egúngún ṣe má n jó kiri ìgboro Ikunlẹ Abiyamọ o, èèyàn mẹfa pàdánù ẹmi wọn, èèyàn mẹsan farapa ninu ìjàmbá ọkọ kan to waye ni Lekki-Epe Ẹ gbọ naa o, kí ló ń fa awuyewuye, gbas-gbo láàrín àwọn ọmọ ọba Àwùjalẹ̀ lórí ẹni t'ọ́ba tọ́ sí. Ko s'ẹni to ju ofin lọ, Ààrẹ yọ adájọ́ àgbà nípò lórí ẹ̀sùn àṣìlò ipò tí àráàlú kan fi kàn án