У нас вы можете посмотреть бесплатно Àrànbádá | Reverend Bode Johnson или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Ní ìgbà míì, a ní àwọn ìfẹ́ ọkàn, ṣùgbọ́n a le má nìí ipá tàbí agbára láti mú won wá sí ìmúse Ìdènà tàbí àìlágbára láti ṣe ohun tí a fẹ́ a máa duni lópòlopò, pàápàá jùlọ nígbà tí ọkàn wa ń fẹ́ láti ṣe. Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run fi ń mú ọ̀rọ̀ yìí wá sí ọ lónìí. Nínú Àjòdún ororún [Festival of Hundreds (FOH)] ti òní, Rev. Jay mú ìwaasu Yorùbá alágbára kan wá sí wa tí a pè ní *“Àrànbádá”*, ìwaasu yíì wá láti mú wa dé ibi ìmúṣẹ àwọn ìlérí àti ìfẹ́ ọkàn wa nípa asọtẹ́lẹ̀. Ẹ gbọ́o lónìí, kí Ọlọ́run bù kún yín, kí ẹ sì máa bù kún àwọn ẹlòmíràn. Ọlọ́run á bù kún yín! Ẹ má ṣe gbàgbé láti fẹ́ràn (like) fídíò yìí, fi èrò okàn yin sí i (comment), kí ẹ sì pín (share) fún àwọn ẹlòmíràn. Máa rí yín lọ́la. #aranbada #yorubasermon #yoruba #oreofe #christian #christiansermon