У нас вы можете посмотреть бесплатно ILE IRAN LO WA NIDI IGBESUNMOMO L'ORILEEDE NIGERIA - ASOJU ILE ISRAEL FREEMAN LO SORO SOKE BEE или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
ILE IRAN LO WA NIDI IGBESUNMOMO L'ORILEEDE NIGERIA - ASOJU ILE ISRAEL FREEMAN LO SORO SOKE BEE Ilẹ Iran lo wa nidi igbesunmọmi l'orilẹede Naíjíríà - Aṣoju ilẹ Israel Freeman lo sọrọ soke bẹẹ Tinubu jẹni ire ni o laduru eebu ti mo bu pẹlu abuku ti mo fi kan sibẹ o fori ji mi, o fun mi lominira taba wa ri ẹni to ni bi mo ti satilẹyin fun o daa, a jẹ pe alaimoore ẹda niiru ẹni bẹẹ. Sunday Igboho lo sọrọ soke bẹẹ. Orileede Nàìjíríà si ma bori awọn agbesunmọmi o, boti le jẹ wọn sekolu ni ipinle Borno laipe - Tinubu lo soro ikiya náà fun awon ologun be. Awọn aráàlú kọminu lori bi wọn se tun f'owó kun owó epo bẹntiroolu, Ileesẹ ifọpo Dangote yin owó epo bẹntiroolu ti ẹ sókè sí N995 ni jala epo kan O dojú ẹ o, Awọn Agbesunmọmi tun ji èèyàn mẹwàá gbe salọ nipinlẹ Kwara Ọdún Ọba Onpetu gbogbo ilẹ Ijeru dun ogbọngbọn kan si o fun bi Kabiesi se jawe oye Asiwaju gbogbo ilẹ Ijeru Kingdom le alagba Isaac Adebayo Akinkunmi lori “Yoruba News Today | Ìròyìn Tuntun Lónìí” “The Voice of Yoruba Worldwide” DriveTv Yoruba is a trusted global source for Yoruba news and in-depth analysis. We deliver accurate, timely, and engaging news updates in Yoruba, connecting Yoruba communities in Nigeria and across the world — including the United Kingdom, United States, and Canada. Our mission is to inform, educate, and unite Yoruba people worldwide through credible journalism and meaningful conversations.