У нас вы можете посмотреть бесплатно Orin Etíyerí - Ewi alohùn ajẹmọ ayẹyẹ или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Jẹ́ ká kọ́ Yorùbá Orin Ẹ̀tíyẹrì Orin ẹ̀tíyẹrì jẹ́ orin ìbílẹ̀ Yorùbá tí a máa ń lò láti kí, Ó sábàa kún fún ọgbọ́n, ìkìlọ̀, ìtàn ìgbésí ayé, àti ìmọ̀lára. Àwọn Àbùdá Orin Ẹ̀TÍYẸRÌ ( FEATURES) 1. Èdè pẹlẹbẹ àti àrọ́kọ – Ó máa ń lo owe, àpẹẹrẹ, àti àfihàn. 2. Ìlù ìbílẹ̀ – Bíi bàtá, dùndún, gángan. 3. Lílé àti gbígbè– Olórin le, àwọn elégbè yóò sì gbè é. 4. Ìtàn àti ìtọ́́nisọ́nà – Kí ènìyàn kọ́ ẹ̀kọ́ nínú rẹ̀. Ìdí Tí A Fi Máa Kọ Orin #highlight #òweyorùbá #èdèyorùbá #ẹ̀kọ́yorùbá Ẹ̀TÍYẸRÌ (Reasons) Látí kó ìmọ̀ àti ìtàn ìbílẹ̀ kọjá sí iran tuntun 1. Látí kí ẹni tàbí ìṣẹ̀lẹ̀ 2. Látí kìlọ̀ tàbí kọ́ni ní ìwà rere 3. Látí mú ayọ̀ wá ní ayẹyẹ 4. Láti fi dẹ́kun ìwà ibajey Àwọn Àpẹẹrẹ Ìlò ( Where its being use) 1. Ayẹyẹ ìgbéyàwó 2. Ìkórè tàbí àjọyọ̀ 3. Ìpàdé àwùjọ 4. Eré ìbílẹ̀ Ìtóbi Orin Ẹ̀tíyẹrì Nínú Àṣà Yorùbá ( Importance) Orin ẹ̀tíyẹrì ń pa àṣà mọ́, ń kọ́ ìwà, ń sì sọ̀kan àwùjọ. Ó jẹ́ apakan #africanlanguage pàtàkì nínú ìdánimọ̀ Yorùbá. Ìpinnu (Ìkẹyìn) Orin ẹ̀tíyẹrì kì í ṣe orin lasan; ó jẹ́ ọ̀nà ìkó ìmọ̀, ìtàn, àti ìwà rere fún awùjọ Yorùbá.