У нас вы можете посмотреть бесплатно Ifinijoye Aláàfin Abimbola Owoade или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Àti Yan Prince Akeem Abimbola Owoade gẹgẹ bí Oba Ogoji lẹ ni mefa, Alaafin ti Ilu Oyo, awon ni won bo sì ipo ti Oloogbe Oba Lamidi Adeyemi III kuro lori re. Ayeye yi wáyé lẹyìn osu meta ti ijoba ipinle naa ti yan wan. O waye ni papa ile eko Olivet Baptist High School to wa niluu Oyo. Lara awon eeyan oloye bii Gomina Seyi Makinde, Aare Asiwaju Tinubu sí ran Mínísítà Bayo Adelabu ki owa se oju rẹ. Awọn agbọrọsọ ṣe afihan pataki itan ti itẹ ati ipa ti aṣa. Gomina Makinde tẹnumọ isokan, Alaafin tuntun ninu ọrọ akọkọ rẹ, pe fun igbese apapọ lati mu ilọsiwaju ati iyipada rere. English Translation Prince Akeem Abimbola Owoade I has been officially crowned the 46th Alaafin of Oyo, succeeding the late Oba Lamidi Adeyemi III. The coronation ceremony, held three months after his selection by the state government, took place at Olivet Baptist High School ground in Oyo. Attended by dignitaries including Governor Seyi Makinde and President Tinubu's representative, Bayo Adelabu, the event was rich in culture. Speakers highlighted the throne's historical importance and the role of tradition. Governor Makinde stressed unity, while the new Alaafin, in his first address, called for collective action to drive progress and positive change.