У нас вы можете посмотреть бесплатно Ẹ̀sì Ọ̀rọ̀ Dẹ̀ Látí Ẹnu Baba Mufty Ilorin Sí Baba Lagege Lórí Ọ̀rọ̀ Sheikh Al-Miskinubillahi или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Fidio yìí jẹ lecture pataki látọ̀dọ̀ Baba Mufty Ilorin, níbi tí ó ti sọ̀rọ̀ lórí ọ̀rọ̀ tí ó kan Baba Lagege àti Sheikh Al-Miskinubillahi. Ọ̀rọ̀ yìí ti fa ariyanjiyan láàrín àwọn Musulumi, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì fẹ́ mọ: Kí ni gangan ṣẹlẹ̀? Kí ni ìdí tí ariyanjiyan yìí fi pọ̀ tó bẹ́ẹ̀? Kí ni ìtúmọ̀ ọrọ Baba Mufty Ilorin? Nínú lecture yìí, Baba Mufty ṣàlàyé ọ̀rọ̀ náà pẹ̀lú ẹ̀rí àti ìtọnisọna fún ìṣọ̀kan àwọn Musulumi. 📌 Wo fidio náà títí dé opin kí o lè lóye gbogbo ọrọ náà dáadáa. 👍 Like fidio yìí 💬 Comment èrò rẹ 🔔 Subscribe fún àwọn lecture Islam tuntun. #MuftyIlorin #BabaLagege #SheikhAlMiskinubillahi #IlorinIslam #IslamNiYoruba #IslamicLecture #YorubaIslam #IlorinEmirate