У нас вы можете посмотреть бесплатно itan ile yoruba (ALAFIN OYO )AND (ONI IFE) TRUTH STORY (@yorubanikan) или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Ìtàn gidi nípa bí Ọòni àti Aláàfin ṣe dá sílẹ̀ láti ìgbà Odùduwà. Nigbati Odùduwà dé Ilé-Ifẹ̀, ó rí ọ̀pọ̀ ènìyàn níbẹ̀, ó sì lò ọgbọ́n àti àyè láti di ọba. Lẹ́yìn náà, ó rán gbogbo ọmọ rẹ̀ káàkiri láti di ọba ní orílẹ̀-èdè wọn. Ṣùgbọ́n nígbà tí Odùduwà kú, àwọn ènìyàn tí ó bá pàdé ní Ilé-Ifẹ̀ ṣáájú rẹ̀ gba àṣẹ wọn padà. Ìtàn yìí fi hàn pé Ọlọ́run fún gbogbo ènìyàn ní ẹ̀tọ́ wọn padà. 📚 Ẹ wo fidio yìí kí ẹ mọ ìtàn àtàwọn àṣà Yorùbá dáadáa. 🔔 Ẹ má ṣe gbàgbé láti subscribe fún ìtàn tuntun ní gbogbo ọ̀sẹ̀. #YorubaNikan #Ooni #Alaafin #Oduduwa #YorubaHistory #IleIfe #OyoEmpire #AsiriIfe #YorubaCulture #YorubaKing #NigeriaHistory #yoruba # #YorubaTradition #Odua #YorubaHeritage