У нас вы можете посмотреть бесплатно StPeter's Churchfaji Live Stream или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Join us Live St Peter's Church, Faji, Lagos Diocese of Lagos (Anglican Communion) 10.00A.M - ISIN OWURO - (IDANILEKO) OLUDARI - THE REV. TIMOTHY OLUSANYA. AKORI ORO: IGBARADI SILE NIPASE ISODOTUN IRAN TI KRISTI OJO ISIMI KETA SAAJU LENTI (SEPTUAGESIMA) Oro Akoso: Enikeni ti o ba npa ofin re mo, lara re li a gbe mu ife Olorun pe nitoto. I John 2:5. Kolekti Fun Ose: Olorun ayeraye, Eniti Omo Re Jesu Kristi je ona, otito ati iye fun gbogbo araye: Fifunni ki a le rin ni ona Re, ki a le yo ninu otito Re, ki a si le se alabapin ajinde Re, Eniti O wa ti O si njoba pelu Re ati Emi Mimo, Olorun kan aye ainipakun. Amin. MAJEMU LAELAE - Oba Keji 2:1-12 (Guild of Stewards) EPISTELI - 2 Kor. 4:3-6 (Mr Ademola Akande) IHINRERE - Marku 9:2-9 (Alufa Ijo) IWAASU - The Rev. Canon Diran Ogundipe ADURA DE ORE-OFE - The Ven. Joshua Oladejo THE VICAR: The Ven. Dr Festus Oluwole Ajayi THE DIOCESAN BISHOP : The Rt. Rev’d Dr. Ifedola Gabriel Senasu Okupevi. Follow us at St. Peter's Church, Lagos On: Youtube: / Канал Facebook: / 1z7tq6qmav Kindly bless someone by sharing this. God bless you!