У нас вы можете посмотреть бесплатно ODALE NI JIDE KOSOKO, EMI NI OLOJA ILU EKO TI WON YAN - ABIOLA OLOJO - KOSOKO или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
ODALE NI JIDE KOSOKO, EMI NI OLOJA ILU EKO TI WON YAN - ABIOLA OLOJO - KOSOKO Ìjọba àpapọ̀ ti kọminú o lórí bí àwọn ọmọ Naijiria kan ṣe ń lọ jagun nílẹ̀ òkèrè láì mọ̀. O ma wa ga o, awọn agbébọn tun sekọlu si ìlú mẹ́ta ní Niger, ṣekúpa èèyàn Ọgbọn, dáná sun ilé àti àgọ́ ọlọ́pàá nipinlẹ Niger. Ìkọ Amọtẹkun nawọ gan awọn Afurasí Ajinigbe mejila, at'awọn metalelọgọrin mii l'Ondo Haa! Èèyàn mẹrin jẹ jijigbe salọ ninu ikọlu tuntun mii nilu Kwara Lowuro ojọ Aje Monday oko ero bus to n ko eja odo rinrin ajo ni ìjàmbá lopópónà Ogbomoso s'Oyo opọ dukia sofo pẹlu emi èèyàn. Ọdàlẹ ni Jide Kosoko, Emi ni Oloja Ilu Èkó tí wọn yan - Abiola Olojo-Kosoko. Ìjọba àpapọ̀ gbé El-Rufai lọ iléẹjọ́ lórí ẹ̀sùn titọwọbọ ibanisọrọ ori fóònù Nuhu Ribadu