У нас вы можете посмотреть бесплатно Hymns with Yinka Erinle или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Hymns with Yinka Erinle Studio : Vita Studios Visuals : Richielens_ Mixing and Mastering: Dnath @Dnathdrums Hymns OLORI ijo t’ orun, L’ ayo l’ a wole fun O; K’ o to de, ijo t’ aiye, Y’o ma korin bi t’ orun, A gbe okan wa s’ oke, N’ ireti t’ o n’ ibukun; Awa kigbe, awa f’ iyin F’ Olorun igbala wa. APATA aiyeraiye, Se ibi isadi mi! Je ki omi on eje T’ o san lati iha Re Se iwosan f’ ese mi, K’ o si so mi di mimo. JESU nigba ‘danwo, Gbadua fun mi; K’ emi ma ba se O, Ki nsi sako lo: ‘Gba mba nsiyemeji, K’ o bojuwo mi; K’ eru tab’ isaju, Ma mu mi subu. B’ o bap on mi l’ oju, Ninu ife Re; Da ibukun Re le, Ori ebo na: Ki nf’ ara mi fun O Lori pepe Re; B’ ara ko ago na Igbagbo y’o mu. Great is Thy faithfulness,” O God my Father, There is no shadow of turning with Thee; Thou changest not, Thy compassions, they fail not As Thou hast been Thou forever wilt be. Great is Thy faithfulness!” “Great is Thy faithfulness!” Morning by morning new mercies I see; All I have needed Thy hand hath provided— “Great is Thy faithfulness,” Lord, unto me! EJE k’ a f’ inu didun, Yin Oluwa Olore; Anu Re, o wa titi, L’ ododo dajudaju. ONISEGUN nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni l’ ara da, A, gbo ohun ti Jesu! Iro didun l’ orin Seraf’, Oruko didun li ahon, Orin t’ o dun julo ni, Jesu! Jesu! Jesu! ORE-OFE! Ohun Adun ni l’ eti wa; Gbongbon re yio gba orun kan, Aiye o gbo pelu. Ore-ofe sa, N’ igbekele mi; Jesu-ku fun araiye, O ku fun mi pelu. ISUN kan wa t’o kun f’eje O yo n’iha jesu, Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi. IGBAGBO mi duro l’ori, Eje at’ododo Jesu; Nko je gbekele ohun kan, Lehin oruko nla Jesu; Mo duro le Krist’Apata, Ile miran, iyanrin ni. Then sings my soul, My Savior God, to Thee, How great Thou art! How great Thou art! Then sings my soul, My Savior God, to Thee, How great Thou art! How great Thou art! No pow'r of hell, no scheme of man can ever pluck me from His hand; 'til He returns or calls me home, here in the pow'r of Christ I'll stand! Amen !