У нас вы можете посмотреть бесплатно GANI ADAMS, ALAAFIN OYO, AFENIFERE KORO OJU SI IPANIYAN TO N WAYE NI KWARA BEERE AABO FUN ILE YORUBA или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
GANI ADAMS, ALAAFIN OYO, AFENIFERE KORO OJU SI IPANIYAN TO N WAYE NI KWARA BEERE AABO FUN ILE YORUBA Iku to n pa ojugba ẹni, owe lo n pa fun ni o, Gani Adams, Aláàfin Oyo, Afẹnifẹre lapapọ korò ojú sí ìpànìyàn to n waye Kwara, beere ààbò to gbopọn fún ilẹ̀ Yorùbá Haa! Ọgá agba àjọ ẹṣọ ẹni laabo-ilu Civil Defence nípinlẹ Edo, ṣubu lulẹ, padanu ẹmi rẹ l'ode ariya Ojiji lo ba mi o, Ojú oorun ni mo wa ti Aláàfin mi pé wọ́n ti yan òun ní ọba, laimọ tẹlẹ pé ìdílé ọba ló ti wá ká tó ṣe ìgbéyàwó - Olori Alaafin Ọwọade lo salaye ọrọ bẹẹ. Baba to kuna láti tọ ọmọ rẹ - Ìyàwó Oluwo tẹlẹ lo sọko ọrọ sí Oluwo bẹẹ lori ẹsun eke to fi kan Ọọni Ile-Ifẹ Awọn Olùgbé-ilu bu ẹnu àtẹ lù ijọba ipinlẹ Kwara lori bo se n pa àwọn olùgbé ilu lẹnumọ lẹyìn ọpọ isekupani to waye nijọba ibilẹ Edu ati Patigi Baba Mohbad bèèrè ki wọn sedajọ fún ìyàwó Mohbad ati Nọọsi alabẹrẹ to lọwọ ninu iku olóògbé lori iwa aibikita wọn