У нас вы можете посмотреть бесплатно IMAM OGBOMOSO, Ẹ GBỌ́ DÁADÁA! ⚠️ Ọ̀RỌ̀ ÒṢÙ AWE RAMADAN TÍ Ó Ń GBÓNÁ LÓRÍ AYÉLUJÁRA или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Nínú fídíò yìí, a gbé ikílọ̀ pàtàkì kalẹ̀ fún Imam Ogbomoso lórí ọ̀rò Òṣù Awe Ramadan tí ó ti ń dá àríyànjiyàn sílẹ̀ láàárín àwọn Musulumi. 👉 Kí ni Òṣù Awe Ramadan gan-an? 👉 Ṣé ó ní ìtẹ́wọ́gbà nínú Qur’an àti Sunnah? 👉 Kí ni ipa rẹ̀ lórí ìjọba Musulumi àti àlàáfíà Ummah? Fídíò yìí jẹ́ ìkìlọ̀ pẹ̀lú ìmọ̀ràn, kì í ṣe ìkórìíra. A ń pè fún ọgbọ́n, ìṣọ̀kan, àti ìbẹ̀rù Ọlọ́run nínú gbogbo ohun tí a bá ń sọ nípa Islam.. 📌 Ẹ wo títí dé opin 📌 Ẹ sọ èrò yín nínú comment 📌 Ẹ subscribe, like & share kó le dé ọdọ́ ọ̀pọ̀ Musulumi míì.