У нас вы можете посмотреть бесплатно HAA! INA SEYO LAAFIN EMIR - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
HAA! INA SEYO LAAFIN EMIR - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY Mo kabamọ pe mo jẹ ọkan lara awọn to da ẹgbẹ oṣelu olosusuọwọ APC silẹ - Atiku lo sọrọ soke bẹẹ Haa! Ina sẹyọ láàfin Emir Jama'a ni Kaduna Àwọn Agbebọn tun ṣọọṣẹ laabi wọn o, wọn ji ọpọ olùgbé-ilu Kogi nitosi Ileewe Government Technical College gbe salọ Ọdọmọdekunrin kan ganu s'atimọle Ọlọpa fẹsun fifipa ba Ọdọmọdebinrin lajọsepọ Mo di alagbe- ẹni to n tọrọ jẹ lẹyìn ìjàmbá ina - Ọkunrin Eko kan lo kọminu bẹẹ Ẹ tu ìgbéyàwó wa ka o- Ọkọ mi ma n fi ẹsun asemase kan mi, niiṣe lo ma n lù mí, tari mi jade sita ninu otutu l'alẹ - Iyawo kan lo rọ ileẹjọ bẹẹ “Yoruba News Today | Ìròyìn Tuntun Lónìí” “The Voice of Yoruba Worldwide” DriveTv Yoruba is a trusted global source for Yoruba news and in-depth analysis. We deliver accurate, timely, and engaging news updates in Yoruba, connecting Yoruba communities in Nigeria and across the world — including the United Kingdom, United States, and Canada. Our mission is to inform, educate, and unite Yoruba people worldwide through credible journalism and meaningful conversations.