У нас вы можете посмотреть бесплатно ILEESE PAPAKO OFURUFU FE SO KWAME 2 IBOM AIR DI AMBASSADOR - KOSI ESIN KANKAN TO NI'PO OBA O - OLUWO или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
ILEESE PAPAKO OFURUFU FE SO KWAME 2 IBOM AIR DI AMBASSADOR - KOSI ESIN KANKAN TO NI'PO OBA O - OLUWO TILU IWO - YORUBA NEWS Ileesẹ papakọ ofurufu n gbero lati sọ KWAM2 arìnrìnàjò Ibom Air di Ambassador fún iwa rere - Keyamo lo sọrọ jade bẹẹ Mo sì wà nínú ìrora, koda mo nílò ìtọ́jú tó péye, Comfort Kwam2 tó fa wàhálà pẹ̀lú àwọn osisẹ Ibom Air lo sọ̀rọ̀ yi lẹ́yìn tó jáde kuro lọ́gbà ẹ̀wọ̀n Kirikiri O nami lowo o ni n mọ ki ọ, wu yu ẹpu lọrọ ọhun jọ o, Mi o ṣiṣẹ nileeṣẹ jọba tabi taladani, bẹẹni - -- ijọba o fun mi lowo osu, ẹ si ni n ma kowo wa, nn ko wa! Peller fariga lori N36m owo ori ti ijọba ni o gbọdọ san A o ti ri $100,000 ti Ijọba apapọ ṣèlérí fún wa gba o - Balogun ìkọ agbabọọlu Super Falcons lo sọrọ soke bẹẹ Kòsí ẹ̀sìn kankan tó ni'pò Ọba o, Ìsẹ̀se, Musulumi tabi Kristiẹni kọ́ lonì Ọba, kí ẹnikẹni má pọn dandan èsìn kan lé Ọba lórí Oluwo tilẹ Iwo lo sọ bẹ. Alaye ọrọ re o, nipa iṣẹlẹ yìnyínbọn sekupa akẹkọ̀ọ́ ileewe gíga LAUTECH lọjọ Sign Out l'Ògbómọ̀ṣọ́ O d'ofin o, ileewe giga kankan o gbọdọ lalẹ wu lọdun meje sasiko yi, Ijoba apapọ lo fọnrere bẹ