У нас вы можете посмотреть бесплатно HAA! AWON AGBEBON JI IMAAMU BABANLA ATI AWON MERIN MII GBE SALO NI KWARA - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
HAA! AWON AGBEBON JI IMAAMU BABANLA ATI AWON MERIN MII GBE SALO NI KWARA - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY Iran yan Motjaba Khamenei ọmọ Ayatollah Ali Khamenei gẹgẹ bi Adari tuntun Haa! Àwọn agbébọn jí Ìmáàmù Babanla àti àwọn mẹ́rin míì gbé salọ nipinlẹ Kwara Adarí ilẹ Iran to kan ko ni pẹ lori ipo láìsí ibuwọlu Ilẹ Amẹ́ríkà - Ààrẹ Trump lo sọrọ soke bẹẹ Ilẹ Iran loun ti ṣetan o, lati ṣàtìlẹyìn fún Nàìjíríà nípa gbigbogunti igbesunmọmi - Aṣoju ilẹ Iran lo sọrọ soke bẹẹ Ọgá Agba Ọlọpa buwọ́lù Anthony lati rọ́pò Benjamin Hundeyin gẹ́gẹ́ bíi Alukoro iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Naijiria Oloye Sunday Igboho gba àwọn aṣojú ìjọba Nàìjíríà tuntun sílẹ̀ òkèèrè lámọ̀ràn, Ó ní kan bá Ààrẹ Tinubu ṣíṣẹ́ pọ̀ láti yí orúkọ Naijiria padà sí rere Máa fi gbogbo aye mi satilẹyin fun baba Tinubu, yoo si wọle saa keji tori òun ló yọ okùn tí Buhari fi sí mi lọ́rùn kúrò - Sunday Igboho Ooṣa lo sọrọ jade bẹẹ Ileesẹ Àjọ Civil Defence ṣètò láti pèsè ìkọ oṣiṣẹ alaabo 11,000 lojuna lati daabobo awọn àgbẹ lọwọ ikọlu E gbo kí ló máwọn afurasí jàndùkú olóṣèlú ya wọ ilé Igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo tẹ́lẹ̀ n'Ibadan, ba ọ̀pọ̀ dúkìá jẹ́, se ọpọ èèyàn lese. “Yoruba News Today | Ìròyìn Tuntun Lónìí” “The Voice of Yoruba Worldwide” DriveTv Yoruba is a trusted global source for Yoruba news and in-depth analysis. We deliver accurate, timely, and engaging news updates in Yoruba, connecting Yoruba communities in Nigeria and across the world — including the United Kingdom, United States, and Canada. Our mission is to inform, educate, and unite Yoruba people worldwide through credible journalism and meaningful conversations.