У нас вы можете посмотреть бесплатно O MA TUN DO JU E BAYII O! BI AWON AGBEBON TUN SE KOLU ILE IJOSIN,PA IYAWON PASITO,JO OPO OKO NINA или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
O MA TUN DO JU E BAYII O! BI AWON AGBEBON TUN SE KOLU ILE IJOSIN,PA IYAWON PASITO,JO OPO OKO NINA Ó má ti wá dó ju ẹ̀ báyìí o, pẹ̀lu bí àwọn agbébọn tún se kọlu ilé ìjọ́sìn, pa ìyàwó pásítọ̀, jó ọ̀pọ̀ ọkọ̀ níná, bakan náà ṣe ọ̀pọ̀ èèyàn lèṣe Àlàyé rèé o, lórí ìdí tí wọn ṣe lé odidi ọba, ẹni ọdún metadinlogoji 37 kúrò láàrin ìlu, gbẹ́sẹ̀ lé ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ rẹ̀. Àwọn Agbebọn sekilọ fún wa pé ká má pariwo: Awọn Akẹkọ̀ọ́ alakọbẹrẹ ti wọn doola lo sọrọ jade bẹẹ nipa ohun tójú wọn rí nigbekun awọn ajinigbe Àjọ ẹṣọ ẹni laabo-ilu Civil Defence nawọ gan ọkọ akẹru kan to n gbe awọn ọmọde mọkanlelogun t'ọjọ ori wọn kere, ti wọn furasi pe wọn fẹ gba wọn wọlé fún idanilẹkọ iwa igbesunmọmi ni Àfàìmọ̀ kọ́rọ̀ yi o ma daapọn o, ìgbésẹ̀ mímú iko omọ ológun mọ̀kànlá sáhàámọ́, gbẹ́sẹ́ lé bàálù ileese ológun ati bi Nàíjíríà ṣe fèsì lórí ìdí tí bàálù rẹ̀ fi balẹ̀ lójijì si agbègbè Sahel Ogun Boko-haram ni Naijiria ti pẹ fún ọdún mẹẹdogun nítorípé Ileesẹ kan ni eto-ààbò to mẹhẹ naa - Obasanjo lo sọrọ soke bẹẹ