У нас вы можете посмотреть бесплатно ESI ORO RE O, REMI TINUBU ATI ADELEKE FESI LORI ISELE GBASGBOS TO WAYE LARIN WON N'ILE IFE или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
ESI ORO RE O, REMI TINUBU ATI ADELEKE FESI LORI ISELE GBASGBOS TO WAYE LARIN WON N'ILE IFE Esi ọrọ re o, Rẹmi Tinubu ati Adeleke fèsì lórí ìsẹ̀lẹ̀ tó wáyé n'Ile Ife Awọn ẹṣọ alaabo nawọ gan arakùnrin kan tó sapamọ sábẹ́ táyà ọkọ bàálù ní pápákọ̀ òfurufú Ilorin pẹ̀lú èròńgbà láti jápa lọ silẹ Amẹrika Ọpẹ o, Otesile Ààrẹ JCI, to tun jẹ ọmọbìnrin Àlùfáà ìjọ n'Ibadan ti ri itusilẹ ominira gba Awọn Akẹkọ̀ọ́, awọn alaṣẹ alamojuto ileewe fọnmu o, lori erekere ìyẹn 'Båndït prånk' ti awọn ọdọkunrin kan ṣe to da lori sise bi awọn agbesunmọmi eyi to jẹ yiya ninu ọgba ileewe gíga ipinlẹ Eko Haa! Ikunlẹ Abiyamọ o, awọn akẹkọ̀ọ́ ileewe gíga UNIJOS mẹjọ pade iku ojiji ninu ìjàmbá ọkọ to waye nipinlẹ Plateau Awọn wọnyí ni mínísítà tó bá Buhari ṣiṣẹ́ tó ń jẹ́jọ́ lọ́dọ̀ àjọ EFCC fẹ́sùn ìwà àjẹbánu Mo si nife ẹgbẹ́ òsèlú PDP o amọ mo ní láti fi ẹgbẹ́ náà silẹ fun idi pataki Gómìnà Adeleke lo salaye orọ bẹ ẹ