У нас вы можете посмотреть бесплатно AWON AGBEBON TUN SEKOLU S'AWON AGBE L'ONDO - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
AWON AGBEBON TUN SEKOLU S'AWON AGBE L'ONDO - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY Àwa kọ́ la bẹ̀rẹ̀ ogun pẹ̀lú Iran, ṣùgbọ́n àwa la máà fòpin síi – Hegseth, alákóso ètò àbò nílẹ̀ Amẹ́ríkà lo sọrọ jade bẹẹ Ẹni ti yóò di Adari orílẹ-èdè Iran bayi yóò buru ju ti Khamenei lọ - Àlùfáà Primate Ayodele lo sọrọ soke bẹẹ Haa! Awọn Agbébọn tun ṣekọlù s'awọn Àgbẹ meji, sekupa ọkan l'Ondo Gbajúmọ̀ Ayàwòrán ati Awalupupu ọmọ Nàìjíríà, Kola Onifoto pade iku ojiji lẹyin to nìjàmbá l'Eko O dojú ẹ o, Awọn Ajagunta Ìkọ ISWAP ṣekọlù s'ilu Yobe, dana sun ọja Gaidam bi awọn Ìkọ Olóògùn ṣe n gbogunnti awọn Agbesunmọmi PDP kò tí ì kọ́gbọ́n o won si ma to gbon, ẹ̀yìn Tinubu ni mo ṣì wà fún 2027-Nyesom Wike lo so be. Ileesẹ Ọlọ́pàá nawọ gan afurasi kan, wọn sì ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lori ìkú 'Obesere' olórí ọ̀dọ́ tí agbébọn jí gbé l'Ondo “Yoruba News Today | Ìròyìn Tuntun Lónìí” “The Voice of Yoruba Worldwide” DriveTv Yoruba is a trusted global source for Yoruba news and in-depth analysis. We deliver accurate, timely, and engaging news updates in Yoruba, connecting Yoruba communities in Nigeria and across the world — including the United Kingdom, United States, and Canada. Our mission is to inform, educate, and unite Yoruba people worldwide through credible journalism and meaningful conversations.