У нас вы можете посмотреть бесплатно AWON AGESUNMOMI KO LETA, BEERE FUN OWO ITANRAN OGORUN MILLIONU NAIRA или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
AWON AGESUNMOMI KO LETA, BEERE FUN OWO ITANRAN OGORUN MILLIONU NAIRA #100M S'ILU KEBBI B'awọn aráàlú se dojukọ awọn Agbesunmọmi Lakurawa funrawọn lo ṣokunfa iku awọn olùgbé-ilu mẹtalelọgbọn 33 naa nipinlẹ Kebbi - Ileesẹ Ọlọpa lo sọrọ soke bẹẹ Ìjọba fẹ̀sùn kan ẹgbẹ́ alákatakítí ẹ̀sin Islam pé wọ́n ṣekúpa èèyàn mẹrinlelọgbọn 34 ní àwọn abúlé káàkiri Ileesẹ Ọlọpa Enugu y'abo ibuba awọn ọdaràn, fi gbooro ofin gbe awọn Afurasí mẹẹdogun, wọn rí awọn ohun ijagun ibọn gba pada Ileẹjọ pàṣẹ f'ajọ INEC lati f'orukọ NDP naa silẹ gẹgẹ bí ẹgbẹ oṣelu Awọn agbesunmọmi kọ lẹta s'ilu Kebbi, wọn n bèèrè fún owó ìtanràn ọgọrùn milliọnu naira N100m Ileesẹ olóògùn nawọ gan awọn alabaṣiṣẹpọ to n fi àwọn ohun elo sọwọ s'awọn ìkọ agbesunmọmi Boko-Haram, wọn rí awọn ohun ijagun ibọn, duronu gba kuro lọwọ wọn Wọnyi l'àwọn ohun tuntun tó wà nínú òfin ètò ìdìbò tí Ààrẹ buwọ́lù