У нас вы можете посмотреть бесплатно MO PADANU OMOBINRIN AKOBI MI LATARI AIRI OWO ILEEWOSAN SAN - IBRAHIM CHATTA - DRIVETV YORUBA NEWS или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
MO PADANU OMOBINRIN AKOBI MI LATARI AIRI OWO ILEEWOSAN SAN - IBRAHIM CHATTA - DRIVETV YORUBA NEWS Mo pàdánù ọmọbinrin akọbi mi látàrí airi owo ileewòsàn san, mi l'owó láti fi ra pósí, inu kireti Coca-Cola ni mo sìn si - Ibrahim Chatta lo kọminu bẹẹ Baba Ijesha ṣì wà l'ọ̀gbà ẹ̀wọ̀n o, ko ti ri itusilẹ gba kuro lọgba ẹwọn - Agbẹjọro Baba Ijesha lo takò iroyin ofege to gba ori ayelujara kan bẹ Ààrẹ Trump yarí lórí ìròyìn tó ní ìkọlu America sí Iran kò tu irun kankan Àwọn aláṣẹ Ileewe gíga fasiti KWASU kéde òfin tuntun latari bí àwọn agbébọn ṣe n ja akẹ́kọ̀ọ́ lólè, fipá bá wọ́n lòpọ̀ lawọn agbegbe ileewe naa Mo pàdánù ọmọkùnrin méjì, ọkọ àtàwọn ẹbí mi míì sinu ikọlu, ọmọ mẹ́tàlá ni ọkọ mi fi sílẹ̀ fún mi - Arabinrin kan lo kọminu bẹẹ Gómìnà Alia koro-oju si isekupani awọn Arinrinajo Kano, o pàṣẹ ki wọn nawọ gan awọn aselaabi ọhun