У нас вы можете посмотреть бесплатно A KO NI JUWO SILE FUN IBERU "NO RETREAT NO SURRENDER" - AARE TINUBU FOWO SOYA - YORUBA NEWS TODAY или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
A KO NI JUWO SILE FUN IBERU "NO RETREAT NO SURRENDER" - AARE TINUBU FOWO SOYA - YORUBA NEWS TODAY Eyi tun ga o, Àwọn afurasí agbébọn yín àdó olóró tí kò lóǹkà, sekupa opọ eeyan, ba ọpọ dukia je nigbati awọn èèyàn bi 108 si farapa yanna yanna nipinle Borno A kò ní juwọ́ sílẹ̀ fún ìbẹ̀rù — Ààrẹ Tinubu fọwọ́ sọya bẹẹ Kwankwaso korooju si ibugbamu ado oloro to waye ni Maiduguri, o pe fún ìgbésẹ takò awọn Agbesunmọmi Awọn èèyàn ti yóò dibo lo ni pàdánù ẹ̀mí wọn yi, Eto aabo lo yẹ ko jẹ kókó ohun tí ìjọba àpapọ̀ yóò mú lọkunkundun julọ, Kiise eto ìdìbò ọdún 2027 - Ndume lo ta bana ọrọ naa sígboro ayé bẹẹ Yẹ̀yẹ́ ni wọn fi mi ṣe o nígbà tí ọmọ mi padanu ẹmi rẹ torí mo ṣe àtìlẹyìn fún Tinubu – Remi Surutu lo sọrọ jade bẹẹ Obìnrin Eko kan f'ẹjọ kan Peller, lo ba tun bèèrè fún N395m lori ẹsun ibanilorukọjẹ ati ilòdì sí ìpamọ́ ẹni Ti ki ba s'Ogunwuyi ta tun leni náà to le gbégẹsi tẹsiwaju isejọba Omi Tuntun to n tu awọn èèyàn lara dọkan nipinlẹ Ọyọ. A ti sekupa Olori àwọn oṣiṣẹ aláàbò Ilẹ Iran, Ali Larijani - Ilẹ Israel lo sọrọ jade bẹẹ Sent 6h a “Yoruba News Today | Ìròyìn Tuntun Lónìí” “The Voice of Yoruba Worldwide” DriveTv Yoruba is a trusted global source for Yoruba news and in-depth analysis. We deliver accurate, timely, and engaging news updates in Yoruba, connecting Yoruba communities in Nigeria and across the world — including the United Kingdom, United States, and Canada. Our mission is to inform, educate, and unite Yoruba people worldwide through credible journalism and meaningful conversations.