У нас вы можете посмотреть бесплатно JAQMAL: ÌDÁJỌ́ TÍ Ó LÒ FÚN IMAM OGBOMOSO, ṢÉ ALÉLÒ FÚN MUDIRU MARKAZ? — ALFA ADEBISI ADU” или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
Jaqmal ti lo ìdájọ́ kan fún Imam Ogbomoso, ṣùgbọ́n ìbéèrè ń bẹ lọ́kàn ọ̀pọ̀ ènìyàn: ṣé ìdájọ́ yẹn alélò fún Mudiru Markaz pẹ̀lú? Nínú àlàyé yìí, Alfa Adébísí Adu ṣàlàyé pẹ̀lú ọgbọ́n, ìmúlòlùfẹ́ esin, àti ìbẹ̀rù Allah, pé idájọ́ kì í yan ẹni, kó sì yẹ kó dá lórí ìfẹ́ ara ẹni tàbí ìkórìíra. Eyi jẹ́ ìkìlọ̀, ìtọ́́nisọ́nà, àti ẹ̀kọ́ fún gbogbo Alfa àti Musulumi, kí esin má bà a jẹ́ ní ọwọ́ ariyanjiyan. 📌 Wo dé òpin, sọ èrò rẹ ní comment, kí o sì share fún àwọn tó yẹ. #Jaqmal #ImamOgbomoso #MudiruMarkaz #AlfaAdebisiAdu #Idajo #YorubaIslam #IslamicDebate #MusulumiNigeria