У нас вы можете посмотреть бесплатно ILEESE OLOPA TI FI GBOORO OFIN GBE AWON IKO AMOTEKUN OGUN NIYE LATARI ISEKUPANI NILU,NIPINLE OSUN или скачать в максимальном доступном качестве, видео которое было загружено на ютуб. Для загрузки выберите вариант из формы ниже:
Если кнопки скачивания не
загрузились
НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием видео, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу
страницы.
Спасибо за использование сервиса ClipSaver.ru
ILEESE OLOPA TI FI GBOORO OFIN GBE AWON IKO AMOTEKUN OGUN NIYE LATARI ISEKUPANI NILU,NIPINLE OSUN Ileesẹ Ọlọpa ti fi gbooro ofin gbe awọn ìkọ amọtẹkun ogun niye látàrí isekupani nilu, nipinlẹ Ọsun Haa o mase o, ileesẹ ologun fidi iroyin iku ọkan lara wọn Samson Haruna tiyawo rẹ dana sun mulẹ . Ẹjọ ti mo ba ro, are ni o, Adunni Ade bori ninu ẹjọ ti o pe tako ẹsun pe oun ati Dino n gbekan si n kan funra wọn Christopher Kolade, àgbàọ̀jẹ̀ aláàkóso, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ dágbére f'aye lẹni ọdún mejilelaadọrun, Ààrẹ Tinubu, ati àwọn èèyàn jakanjakan lágbáyé ń se dárò olóògbé Ẹ sì Ileesẹ ìkọ amọtẹkun pada - Ile igbimọ asofin ipinlẹ Ọsun pàṣẹ ki wọn sì ilẹkùn ọfisi amọtẹkun ti wọn gbe ti pa pada ni kiamọsa Irọ ni o - Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní kó si ẹ̀rí majeminso láti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé agbénipa kọlú ọ̀gá agba Àmọ̀tẹ́kùn l'Ọsun